Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ko sí ọjọ kankan ti iṣẹ oloore inu rẹ jẹ eyi ti Ọlọhun nifẹẹ si julọ ti o to awọn ọjọ yii» ìyẹn ni awọn ọjọ mẹwaa akọkọ Dhul Hijjah
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Ẹni ti o ba pa ẹni a gba adehun lọwọ rẹ ko nii gbọ́ oorun alujanna, ati pe dajudaju oorun rẹ wọn maa n gbọ́ ọ lati ijinna ogoji ọdun”
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Dajudaju wọn ri arabinrin kan ti wọn ti pa ninu ọkan ninu awọn ogun ti Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ja, nitori naa, ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ẹni ti o ba jagun lati jẹ pe ọrọ Ọlọhun ni yio leke, oun ni o wa ni oju-ọna Ọlọhun
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu