+ -

عَنْ أَبِي عَبْسٍ عَبْدُ الرَّحْمَنِ بْنِ جَبْرٍ رضي الله عنه أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«مَا اغْبَرَّتْ قَدَمَا عَبْدٍ فِي سَبِيلِ اللَّهِ فَتَمَسَّهُ النَّارُ».

[صحيح] - [رواه البخاري] - [صحيح البخاري: 2811]
المزيــد ...

Láti ọdọ bàbá Absin Abdur-rahman ọmọ Jabr - kí Ọlọhun yọnu si - dájúdájú òjíṣẹ Ọlọhun - kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - sọ pé:
"Gigiṣẹ ẹru kan konii bu fún erukuru ni ojú ọna Ọlọhun ki iná wa jo".

[O ni alaafia] - [Bukhaariy gba a wa] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 2811]

Àlàyé

Òjíṣẹ Ọlọhun (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) fún wa ní ìró idunnu pé ẹni tí eruku bá bo ẹsẹ rẹ mejeeji nígbàtí o njagun sí oju-ọna Ọlọhun pe iná kò ní jó ẹni na.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. ìfunni ní ìró idunnu fún olujagun sí ojú ọna Ọlọhun pe yóò rí ìgbàlà ati àkóyọ níbi Iná.
  2. Anọbi darukọ gigisẹ mejeeji bó ti ẹ jẹ pé erukuru náà yóò kárí gbogbo ara lapapọ; nitoripé ọpọlọpọ awọn olujagun nigbà náà ni wọn nfi ẹsẹ rìn, ti gigiṣẹ wọn yóò sì kó eruku ni gbogbo iṣesí.
  3. Ibn Hajar ṣọ pe: ti o bá ṣe pé kí eruku kan gigisẹ lasan ni yóò ṣe iná leewọ fún ni, bá wo wa ni ti ẹni ti o bá ṣe akitiyan ti o tun lo igbiyanju rẹ, ti o si lo gbogbo oun tó ní nikapa.
Ìtumọ̀ sí èdè mìíràn: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Èdè Indonéṣíà Èdè Uyghur Èdè Bangali Èdè Faransé Èdè Tọ́kì Èdè Rọ́ṣíà Èdè Bosnia Èdè Sinhala Èdè India Èdè Ṣáínà Èdè Páṣíà Èdè Vietnamese Èdè Tagalog Ti Kurdish Èdè Hausa Ti Pọtuga Malayalam Èdè Telgu Ti èdè Sawahili Thai Pashto Assamese Titi Sweden Ìtumọ̀ sí èdè Amharic Ìtumọ̀ sí èdè Dutch Titi èdè Gujarat Ti èdè ìlú Nepal Ti èdè Dari Ti èdè ìlú Romania Ti èdè ilu Hungary الموري Ti èdè Kannada الولوف Ti èdè ìlú Ukraine الجورجية المقدونية الخميرية الماراثية
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn