En Ar


Iṣẹ́ àkànṣe ìwé gbédègbẹ́yọ̀ àwọn Hadiisi Anọbi àti ìtumọ̀ wọn sí èdè mìíràn:

Iṣẹ́ àkànṣe kan ti o pé lati ṣẹṣa awọn ọrọ Anabi ti wọn n paara ninu àkóónú ti Isilaamu ati ṣiṣe àlàyé rẹ ni ọna tí o maa gbà yé yekeyeke ti o sì tó, lẹ́yìn náà ni itumọ rẹ pẹ̀lú ẹwà ti o ga ni ibamu si awọn ìlànà kan ti o péye si awọn èdè alààyè, ati jijẹ ki o wa ni arọwọto ni ọ̀fẹ́ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọ̀nà tí ó bá rọrùn.

Àwọn àfojúsùn:

  1. Iṣe-awari itọkasi agbaye ti o jẹ ọfẹ, ti o ṣe e gbẹkẹle, ti o ti gberu fún àwọn ìtumọ Hadiisi Anọbi sí èdè mìíràn.
  2. Pipese mẹ́mórì ti kọnputa fún titumọ awọn hadiisi si èdè mìíràn sí iwájú àwọn olutumọ èdè ni àsìkò tí wọ́n ba n túmọ̀ rẹ̀ sí èdè mìíràn.
  3. Mímú àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn dé ọ̀dọ̀ àwọn tí a fẹ́ ki o de ọdọ wọn pẹ̀lú gbogbo ọ̀nà ti o bá rọrùn.

Nínú àwọn ìròyìn tí ìwé gbédègbẹ́yọ̀ náà fi dá yàtọ̀:

  1. Kíkó nǹkan tí ó pọ̀ sínú.
  2. Jijẹ ọ̀fẹ́.
  3. Pipọ àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn.
  4. Mímú ìdàgbàsókè ba ti n tẹsiwaju.
  5. Ṣíṣe dáadáa.

Àwọn ìpele kíkójọ ati mímú ìdàgbàsókè ba:

  1. Kíkó ìwé gbédègbẹ́yọ̀ náà jọ pẹ̀lú èdè Lárúbáwá.
  2. Títú ìwé gbédègbẹ́yọ̀ náà sí àwọn èdè mìíràn.
  3. Jijẹ ki ìwé gbédègbẹ́yọ̀ naa wà ni arọwọto àti titẹ ẹ jáde lórí kọnputa..
  4. Mímú ìdàgbàsókè ti n tẹsiwaju bá ìwé gbédègbẹ́yọ̀ naa àti àwọn ìtumọ̀ rẹ̀ sí èdè mìíràn.