عَنْ عَبْدِ اللَّهِ بنِ عُمَرَ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُما:
أَنَّ امْرَأَةً وُجِدَتْ فِي بَعْضِ مَغَازِي النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ مَقْتُولَةً، فَأَنْكَرَ رَسُولُ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَتْلَ النِّسَاءِ وَالصِّبْيَانِ.
[صحيح] - [متفق عليه] - [صحيح البخاري: 3014]
المزيــد ...
Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji-:
Dajudaju wọn ri arabinrin kan ti wọn ti pa ninu ọkan ninu awọn ogun ti Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ja, nitori naa, ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde.
[O ni alaafia] - [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 3014]
Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ri arabinrin kan ti wọn ti pa ni ọkan ninu awọn ogun ti o ja, nitori naa o kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde ti wọn o tii balaga.