Awẹ

6Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 3Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 6

Wọn mọ Isilaamu pa lori nkan márùn-ún
“Ẹni tí ó bá gba aawẹ Ramadan ni ti igbagbọ ati ireti ẹsan ni ọdọ Ọlọhun, wọn maa fi orí ẹsẹ rẹ ti o ṣáájú jin in”
“Ẹni tí ó bá dìde ni oru Laelatul Kọdri ni ti igbagbọ ati ireti ẹsan ni ọdọ Ọlọhun, wọn maa fi orí ẹṣẹ rẹ ti o ṣáájú jin in”
Wọn mọ Isilaamu pa lori nkan márùn-ún
Òjíṣẹ Ọlọhun (kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba) aa maa se igbiyanju ni mẹwa igbẹyin iru igbiyanju ti kii se ninu awọn ọjọ miran
emi ni Dimaam ọmọ Tha’labah, láti ìdílé Banuu Sahd ọmọ Bakr