Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

?Ti oluperun ba sọ pe: Allāhu Akbar Allāhu Akbar, ti ẹnikẹni ninu yin naa wa sọ pe: Allāhu Akbar Allāhu Akbar
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
?Tí ẹ ba ti gbọ ipe irun, ki ẹ yaa maa sọ iru nkan ti oluperun ba n sọ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
?Ẹni ti o ba sọ nigba ti o n gbọ oluperun pe ash-hadu an laa ilaaha illa Allāhu wahdahu laa sharika laHu, wa anna muhammadan ‘abduHu wa rosuuluhu, rodiitu bil Laahi robban wa bi muhammadin rosuulan wa bil Isilaami diina, wọn a fi ori ẹṣẹ rẹ jin in
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
?Ti ẹ ba ti gbọ oluperun ki ẹ yaa maa sọ gẹgẹ bi o ṣe n sọ, lẹyin naa ki ẹ wa ṣe asalaatu fun mi
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Irẹ Bilal, gbe irun duro, fun wa ni ìsinmi pẹlu rẹ”
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu