Irun akigbọrẹ

3Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 1Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 3

“Ẹni tí ó bá dìde ni oru Laelatul Kọdri ni ti igbagbọ ati ireti ẹsan ni ọdọ Ọlọhun, wọn maa fi orí ẹṣẹ rẹ ti o ṣáájú jin in”
Mo ha rakah mẹwaa lati ọdọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-
Ti ẹnikẹni ninu yin ba wọ masalaasi, ki o yaa ki rakaa meji siwaju ki o to jokoo