Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ẹ ko gbọdọ wọ aṣọ alaari, ẹ ko si gbọdọ mu ninu igba wura ati fadaka, ẹ ko si gbọdọ jẹ ninu abọ tí wọ́n fi mejeeji ṣe, nitori pe awọn (keferi) ni wọn ni i laye, tiwa (musulumi) si ni ni ọjọ ikẹyin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ọkunrin o gbọdọ maa wo ihoho ọkunrin, obinrin naa o si gbọdọ maa wo ihoho obinrin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu