+ -

عَنْ أبي سَعيدٍ الخُدريَّ رضي الله عنه قال: قال رسولُ الله صلَّى الله عليه وسلم ِ:
«إزْرَةُ المُسْلمِ إلى نصفِ السَّاق، وَلَا حَرَجَ -أو لا جُنَاحَ- فيما بينَهُ وبينَ الكعبينِ، وما كان أسفلَ منَ الكعبين فهو في النار، مَن جرَّ إزارَهُ بطرًا لم يَنْظُرِ اللهُ إليه».

[صحيح] - [رواه أبو داود وابن ماجه وأحمد] - [سنن أبي داود: 4093]
المزيــد ...

Láti ọdọ bàbá Saheed Al - Khudiryy kí Ọlọhun yọnu sí o sọ pé: Òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá Rẹ má bà s'ọpe :
« Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó»

[O ni alaafia] - [Abu Daud ati Ibnu Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa] - [Sunanu ti Abu Daud - 4093]

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà tí se alaye pé dajudaju sokoto muslim l'ọkunrin ni awan ìsesí mẹta , sokoto ni òun tí yóò bọ ìdajì isalẹ ará ọkunrin: Alakọkọ ni : Èyí tí wan fẹ ni kí o gùn fẹ ìdajì ojúgun rẹ. Ẹlẹẹkeji ni : Èyí tí o lẹtọ lai sí kikorira níbẹ ni pé kí o kọja ìdajì ojúgun titi de kókósẹ méjèjì ' òun náà ni egún gùn méjì Ẹlẹkẹta : èyí tí o jẹ èèwọ pẹlu pé kí o gùn kọja kókósẹ méjèjì, ipaya sí wa lórí rẹ pé kí inan má lọ ṣẹlẹ sí , tí o ba se pé o se bẹ ni tí moto moto àti ìyá yọ pọra àti ikọja aala Ọlọhun kòní siju aanu wó .

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ìròyìn yí àti ìlérí yí da wa lọtọ fún awan ọkunrin ṣugbọn awan obìnrin , wàn se adayanri wàn kúrò níbẹ , nítorípé wàn tí pa wàn lasẹ láti bọ gbogbo ará wàn .
  2. Gbogbo nkán tí o ba le bọ ìdajì isalẹ ará ni wàn pé ni Izar tàbí , gẹgẹ bí sókótó, àti aṣọ àti nkan mí tí o yatọ sí awan méjèjì, o sí ti wa nínú awàn ìdájọ òfin ẹṣin tí wan tí sọ nípa rẹ nínú Hadith yí .
Ìtumọ̀ sí èdè mìíràn: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Èdè Indonéṣíà Èdè Bangali Èdè Faransé Èdè Tọ́kì Èdè Rọ́ṣíà Èdè Bosnia Èdè Sinhala Èdè India Èdè Ṣáínà Èdè Páṣíà Èdè Vietnamese Èdè Tagalog Ti Kurdish Èdè Hausa Ti Pọtuga Èdè Telgu Ti èdè Sawahili Thai Pashto Assamese Ìtumọ̀ sí èdè Amharic Ìtumọ̀ sí èdè Dutch Titi èdè Gujarat Ti èdè Dari Ti èdè ìlú Romania Ti èdè ilu Hungary Ti ede Madagascar Ti èdè ìlú Ukraine الجورجية المقدونية الخميرية الماراثية
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn