Ilana rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nibi igbeyawo ati ibasepo pẹlu awọn ara ile rẹ

2Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 2

Mo ha rakah mẹwaa lati ọdọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-
Mo maa n wẹ emi ati Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ninu igba kan naa ti awa mejeeji si jẹ ẹni ti o ni janaba lara, o maa n pa mi láṣẹ, ti maa si ro iro, ti o si maa n sunmọ mi ti mo si jẹ ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu,