Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

1. Ẹ fi mi sílẹ̀ lópin ìgbà tí mo ba fi yin sílẹ̀, dajudaju nnkan ti o pa awọn ti wọn ṣáájú yin run ni ibeere wọn ati iyapa wọn si awọn anabi wọn
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
2. Ẹni ti o ba jagun lati jẹ pe ọrọ Ọlọhun ni yio leke, oun ni o wa ni oju-ọna Ọlọhun
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
3. Ẹ ko gbọdọ wọ aṣọ alaari, ẹ ko si gbọdọ mu ninu igba wura ati fadaka, ẹ ko si gbọdọ jẹ ninu abọ tí wọ́n fi mejeeji ṣe, nitori pe awọn (keferi) ni wọn ni i laye, tiwa (musulumi) si ni ni ọjọ ikẹyin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
4. «Mi o ni ki ẹ bura nítorí pé mo n fẹsun kan yin o, ṣugbọn Jubril wa ba mi o si fun mi ni iro pe dajudaju Ọlọhun ti O biyi ti O gbọnngbọn n ṣe iyanran pẹlu yin ni ọdọ awọn malaika
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
5. Ẹ jẹ ki saafu yin o dọgba, nitori pe didọgba saafu ninu pipe irun lo wa - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
6. Mumini o gbọdọ maa korira muminah, ti o ba korira iwa kan lara rẹ, yio yọnu si omiran lara rẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
7. Ti ẹ ba ti wa si aaye igbọnsẹ yin ẹ ko gbọdọ da oju kọ kibula, ẹ ko si tun gbọdọ da ẹyin kọ ọ, amọ ẹ daju kọ ila oorun tabi iwọ oorun
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
8. Ẹnikẹni ninu yin o gbọdọ fi ọwọ ọtun rẹ mu nkan ọmọkunrin rẹ nigba ti o ba n tọ, ko si gbọdọ fi ọwọ rẹ ọtun ṣe imọra nibi igbọnsẹ, ko si gbọdọ fẹ atẹgun si inu ife imumi
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
9. Dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji si deedee ejika rẹ mejeeji ti o ba ti bẹ̀rẹ̀ irun,
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
10. Al-Lahumma Bā`id Baynī Wa Bayna Khaţāyāya Kamā Bā`adta Bayna Al-Mashriqi Wa Al-Maghribi
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
11. Ṣé ki n sọ ọrọ kan fun yin nipa dajjal, ti Anabi kan ko sọ nipa rẹ ri fun ijọ rẹ? O jẹ olójú kan, o maa mu nnkan ti o da bii alujanna ati ina wa pẹlu rẹ,
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
12. Dajudaju àpèjúwe olubajokoo rere ati olubajokoo burúkú da gẹgẹ bi ẹni ti o gbe almisiki ati eni ti o n fẹ ina alagbẹdẹ - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
13. Ẹ yára si awọn iṣẹ daadaa siwaju ki awọn fitina kan ti yio da bii oru ti o ṣokunkun gan o to de, - 4 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
14. Dajudaju Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - jẹ ẹni ti o ṣe pe ti o ba n kirun yio fi alafo si aarin ọwọ rẹ mejeeji titi ti abiya rẹ mejeeji o fi han
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
15. Dinar (owo) ti o lọla julọ ti ọmọniyan n na ni dinar (owo) ti o na fun awọn ara ilé rẹ, ati owo ti o na lori nkan ọ̀gùn rẹ lọ si oju-ọna Ọlọhun, ati owo ti o na lori awọn ẹmẹwa rẹ ni oju-ọna Ọlọhun
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
16. Eemọ ni alamọri mumini, dajudaju gbogbo alamọri rẹ oore ni, iyẹn o si si fun ẹnikankan ayaafi mumini - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
17. Alaye iwẹ latara janaba
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
18. Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o ba sin, o maa n gbe ọwọ rẹ- tabi aṣọ rẹ- si ẹnu rẹ, ti o maa fi rẹ ohun rẹ nilẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
19. Dajudaju ẹ ma maa tẹle oju ọna awọn ti wọn ṣáájú yin, ni odiwọn ìbú atẹlẹwọ si ibu atẹlẹwọ, ni odiwọn apa si apa
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
20. Ko si àkóràn, tabi fifi ẹyẹ fura mọ aburu, tabi fifi ẹyẹ owiwi fura mọ ìṣẹ̀lẹ̀ àjálù, tabi fifi oṣu Safar fura mọ aburu, ki o si sa fun adẹtẹ gẹgẹ bi o ṣe maa n sa fun kinihun
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
21. Mo fi Ọlọhun bura, ki Ọlọhun fi arákùnrin kan ṣoṣo mọna latara rẹ, o loore fun ẹ ju ki o ni ràkúnmí pupa lọ - 4 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
22. Dajudaju awọn eniyan ti wọn ba ti ri alabosi, ti wọn ko si gba a mu ni ọwọ rẹ mejeeji, o sunmọ ki Ọlọhun fi iya kan lati ọdọ Rẹ kari wọn
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
23. Ṣé ki n tọka yin si nnkan ti Ọlọhun fi maa n pa awọn àṣìṣe rẹ, ti O si fi maa n gbe awọn ipo ga? - 6 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
24. Ṣé ki n fun yin ni iro nipa eyi ti o daa julọ ninu awọn iṣẹ yín, ati eyi ti o mọ julọ ninu rẹ lọdọ Oluwa yin, ati eyi ti o ga julọ ninu rẹ ninu awọn ipo yin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
25. ”O ti jere ti o ba sọ ododo”
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
26. Eyi ti o loore julọ ninu ọjọ ti oorun yọ nibẹ ni ọjọ Jímọ̀
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
27. Imu kan gbolẹ, Imu kan gbolẹ, Imu kan gbolẹ", wọn sọ pé: Tani? Irẹ ojiṣẹ Ọlọhun, o sọ pe: "Ẹni ti o ba obi rẹ mejeeji nigba ogbo, ọkan ninu awọn mejeeji tabi awọn mejeeji ti ko wa wọ alujanna
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
28. àwọn MUFARRIDUUN ti ṣíwájú
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
29. Fiforikanlẹ fun Ọlọhun lọpọlọpọ jẹ dandan fun ẹ, dajudaju o ko nii forikanlẹ fun Ọlọhun ni iforikanlẹ ẹẹkan, afi ki Ọlọhun fi gbé ẹ ga nipo, ki O si fi ba ẹ pa ẹṣẹ rẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
30. Ẹni ti o ba kirun tutu mejeeji o maa wọ alujanna - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
31. Musulumi ti wọn ba bi i leere ninu saare: O maa jẹrii pe ko si ẹnikan ti ijọsin tọ si afi Allahu ati pe dajudaju Muhammad ojisẹ Ọlọhun ni
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
32. Dajudaju Ọlọhun ti O biyi ti O gbọnngbọn maa n tẹ ọwọ Rẹ ni oru lati gba tuuba ẹni ti o ba da ẹṣẹ ni ọsan, O si tun maa n tẹ ọwọ Rẹ ni ọsan lati gba tuuba ẹni ti o da ẹṣẹ ni oru titi oorun o fi yọ ni ibi ti o ti maa n wọ - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
33. Gbogbo ibi ti àwọn eegun ti pàdé pọ ni ara ọmọniyan ni saara jẹ dandan le e lori nibẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
34. Ti Ramadan ba ti de ki o yaa ṣe umurah; tori pe dajudaju umurah inu rẹ ṣe deedee hajj - 2 ملاحظة
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
35. Irẹ ojiṣẹ Ọlọhun, a n ri pe jihad (ijagun si oju-ọna Ọlọhun) ni iṣẹ ti o lọla julọ, ṣe aa nii jagun ni? O sọ pe: «Rara, ṣugbọn jihad (ijagun si oju-ọna Ọlọhun) ti o lọla julọ ni: hajj ti o mọ kanga (ti o jẹ atẹwọgba)
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
36. Mo wa pẹlu Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ni o wa lọ sibi akitan ijọ kan, ti o si tọ ni iduro,
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu