عَنْ المُغِيرَةِ رضي الله عنه قَالَ:
كُنْتُ مَعَ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ فِي سَفَرٍ، فَأَهْوَيْتُ لِأَنْزِعَ خُفَّيْهِ، فَقَالَ: «دَعْهُمَا، فَإِنِّي أَدْخَلْتُهُمَا طَاهِرَتَيْنِ» فَمَسَحَ عَلَيْهِمَا.

Lati ọdọ Al-Mughiirah - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe.
Mo wa pẹlu Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ni irin-ajo kan, ni mọ ba bẹrẹ lati bọ abọsẹsẹ alawọ rẹ mejeeji, ni o wa sọ pe: «Fi wọn silẹ, nitori pe dajudaju mo ti mejeeji bọ ọ ni mimọ ni» ni o wa fi ọwọ pa mejeeji.

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 206

Àlàyé

Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa ni ọkan ninu awọn irin-ajo rẹ, ni o wa ṣe aluwala, Nigba ti o wa débi fifọ ẹsẹ mejeeji, Al- Mughiirah ọmọ Shu‘bah - ki Ọlọhun yọnu si i - na ọwọ rẹ mejeeji lati bọ nkan ti o wa ni ẹsẹ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ni abọsẹsẹ alawọ lati fọ ẹsẹ rẹ mejeeji. Ni Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa sọ pe: Fi mejeji silẹ ma bọ wọn, torí pé dajudaju mo ti ẹsẹ mi mejeeji bọ inu abọsẹsẹ alawọ mejeeji ti mo si wa lori imọra, Ni Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - wa fi ọwọ pa abọsẹsẹ alawọ rẹ mejeeji lati fi jirọ fifọ ẹsẹ mejeeji.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Jijẹ nǹkan ti a ṣe lofin pipa abọsẹsẹ alawọ mejeeji a maa ṣẹlẹ nibi ṣiṣe aluwala latara ẹgbin kekere, amọ wiwẹ fun ẹgbin nla ko si ibuyẹ kuro nibi fifọ ẹsẹ mejeeji.
  2. Pipa o maa jẹ ẹẹkan pẹlu mimu ọwọ ti o ti rin fun omi lọ bọ lori abọsẹsẹ alawọ yatọ si isalẹ rẹ.
  3. Wọn ṣe ni majẹmu fun pipa abọsẹsẹ alawọ mejeeji ki wiwọ rẹ o jẹ lẹyin aluwala ti o pe ti yio fọ ẹsẹ rẹ mejeeji ninu rẹ, ati pe ki abọsẹsẹ alawọ naa o mọ, ki o si tun bo aaye ọranyan nibi ẹsẹ, ki pipa a na o waye nibi ẹgbin kekere, ki o ma jẹ nibi janaba tabi nkan ti o le sọ iwẹ di dandan, ati pe ki pipa naa o maa waye laarin asiko ti a là kalẹ ninu shariah oun naa ni ọjọ kan pẹlu oru kan fun onile ati ọjọ mẹta pẹlu oru rẹ fun arinrin-ajo.
  4. Wọn o fi jọ ibọsẹ alawọ mejeeji gbogbo nkan ti o ba ti le bo ẹsẹ bi ibọsẹ olowuu ati nkan ti o yatọ si i, nitori naa o lẹtọọ lati fi ọwọ pa a.
  5. Didaa iwa Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ati ikọnilẹkọọ rẹ, latari pe o kọ fun Al-Mughiirah lati bọ ibọsẹ alawọ mejeeji, ti o si tun ṣe alaye idi rẹ fun un: Wipe dajudaju o wọ mejeeji ni mimọ; ki ẹmi rẹ le balẹ, ki o si tun mọ idajọ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

58 Èdè
EN English الإنجليزية
UR اردو الأوردية
ES Español الإسبانية
ID Indonesia الإندونيسية
UG ئۇيغۇرچە الأيغورية
BN বাংলা البنغالية
FR Français الفرنسية
TR Türkçe التركية
RU Русский الروسية
BS Bosanski البوسنية
SI සිංහල السنهالية
HI हिन्दी الهندية
ZH 中文 الصينية
FA فارسی الفارسية
VI Tiếng Việt الفيتنامية
TL Tagalog تجالوج
KU Kurdî الكردية
HA Hausa الهوسا
PT Português البرتغالية
ML മലയാളം المليالم
TE తెలుగు التلغو
SW Kiswahili السواحيلية
TA தமிழ் التاميلية
MY မြန်မာ البورمية
TH ไทย التايلندية
DE Deutsch الألمانية
PS پښتو بشتو
AS অসমীয়া الأسامية
SQ Shqip الألبانية
SV Svenska السويدية
AM አማርኛ الأمهرية
NL Nederlands الهولندية
GU ગુજરાતી الغوجاراتية
KY Кыргызча القيرقيزية
NE नेपाली النيبالية
LT Lietuvių الليتوانية
PRS دری الدرية
SR Српски الصربية
SO Soomaali الصومالية
TG тоҷикӣ الطاجيكية
RW Kinyarwanda الكينياروندا
RO Română الرومانية
HU Magyar المجرية
CS Čeština التشيكية
MOS Moore الموري
MG Malagasy المالاجاشية
OM Oromoo الأورومو
KN ಕನ್ನಡ الكانادا
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan الأذربيجانية
UZ O‘zbek الأوزبكية
UK Українська الأوكرانية
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
KMR Kurmancî الكرمنجية