Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

1. Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
2. Nígbàtí ẹnikan nínú yín bá lá àlá tí ó nifẹ sí, dajudaju ala naa lati ọdọ Ọlọhun ni ó ti wá, nitori naa ki ó fi ọpẹ fún Allah (Ọlọhun) lori rẹ, kó sì sọ ọ́ fún ẹniti ó bá fẹ́, ṣugbọn tí ó bá lá àlá tí ó yàtọ̀ sí eleyii, ti kò sì wuu, dajudaju lati ọdọ èṣù ni o ti wá, ki iru ẹni bẹẹ yaa bẹ Ọlọhun fún ààbò àti iṣọ nibi aburu àlá naa, bẹẹ ni ki ó má rọ́ àlá náà fún ẹnikankan, ti kò bati rọ ọ fún ẹnikankan àlá náà kò ní kó ìnira ba a
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
3. Ẹnikẹni ti ó bá ṣamojuto ọmọ obinrin meji tabi tí ó tọ́ wọn dagba titi ti wọ́n fi di ẹni ọkunrin, irufẹ ẹni bẹẹ yóò wá ní ọjọ igbende ti èmi rẹ̀ yóò wà papọ̀" Anọbi pa ọmọnika rẹ papọ̀ mọ́nrawọn
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
4. Ti ki báa ṣe pe kin má ko waala bá awọn olugbagbọ ododo ni - tabi awọn ijọ mi ni - mi o ba pa wọ́n laṣẹ lati máa rin pako ni gbogbo asiko Irun kọọkan
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
5. Kosi ọjọ kan ti awọn ẹrusin yóò jí ní àárọ̀ ayaafi kí ó jasipe awọn malaika (iranṣẹ Ọlọhun) meji yoo sọkalẹ sí ọdọ ẹnikọọkan, ọkan ninu awọn mejeeji yóò máa ṣọ pe: "Irẹ Ọlọhun dakun bá mi ṣe iropo owo fún ẹni tí n nawo rẹ, bẹẹ ni ikeji yóò máa ṣọ pe: "Bami fi iparun ati ibajẹ sinu owo ẹni tí ó kọ̀ lati ma na owo, tí ó wowọ́ mọ́n owo kankan
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
6. ẹ má ṣe bú atẹgun , yi e bá rí nkankan ti ko wù yín e sọ bayi pe: " irẹ Ọlọhun àwa n'bere òòrè ti wà lára atẹgun yí lọdọ rẹ àti oore tó wà nínú rẹ àti oore nkan ti wan pàá lasẹ, anwa idaabobo lọdọ rẹ níbi aburú afẹfẹ yí ati aburú nkan ti wa nínú rẹ ati aburú nkan ti wan pàá lasẹ,
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu