Awọn ẹkọ kika al-Quraani alapọnle

1Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 1

“Ẹni tí ba n ka Kuraani sókè da gẹgẹ bii ẹni ti n ṣe sàárà gbanngba, ẹni tí n ka Kuraani jẹ́ẹ́jẹ́ da gẹgẹ bii ẹni ti n ṣe saara kọ̀kọ̀”