عَنْ ابْنِ عَبَّاسٍ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُمَا أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللَّهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«إنَّ اللَّهَ تَجَاوَزَ لِي عَنْ أُمَّتِي الخَطَأَ وَالنِّسْيَانَ وَمَا اسْتُكْرِهُوا عَلَيْهِ».
[قال النووي: حديث حسن] - [رواه ابن ماجه والبيهقي وغيرهما] - [الأربعون النووية: 39]
المزيــد ...
Lati ọdọ ọmọ Abbas kí Ọlọhun yọnu sí awan méjèjì dájú daju òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá rẹ máa ba sọ pé:
« Dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro aṣiṣe àti ìgba gbé fún mi nípa awan ìjọ mí àti nkán tí wan ba jẹ wàn nípa láti ṣe ».
[قال النووي: حديث حسن] - [رواه ابن ماجه والبيهقي وغيرهما] - [الأربعون النووية - 39]
Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà nfun wa niro pé dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro nkán mẹta fún awan ìjọ rẹ : Alakọkọ ni : aṣiṣe, òun ni nkán tí o ba ṣẹlẹ láti ọdọ wàn lai mọn mọn se , òun ni kí muslimu ni ero pẹlu nkán tí o se , kí o wa jasi pe iṣẹ rẹ tí o se se alaba pàdé nkàn tí o yatọ sí nkan tí o gba lérò. Ẹlẹẹkeji ni : igbagbe, òun ni kí muslim se ìrántí nkán kan , ṣugbọn kí o tún gbà gbé rẹ nigbati o fẹ se , kò sí ẹsẹ fún nípa rẹ bákan náà. Ẹlẹkẹta ni : ijeni nípa se nkán, wàn le jẹ ẹrú ( ọmọ ènìyàn) nípa láti ṣe nkan tí kò fẹ se pẹlu pé koni ìkápá láti dá ijẹnipa náà padà , nígbà náà kòní sí ẹsẹ tàbí aburú kàn kan . Pẹlu ise àkíyèsí pé dájú dájú àkòrí ọrọ Hadith ni òun tí bọ nbẹ láàrin ẹrú àti Olúwa rẹ nípa ṣíṣe nkán tí wan se leewọ , ṣugbọn gbígbé nkán tí wan páni lá sẹ jù silẹ ni ti igbagbé kò tí mú aṣẹ náà kúrò, ṣugbọn tí ìwà ọdaran kan ba tí atara ṣíṣee wa ye òun tí o jẹ ẹtọ ènìyàn kò tí bọ , gẹgẹ bí kí o se sí paayan , dandan ni kí o sanwo ìtanràn emi b, tàbí kí o sesi ba mọto jẹ dandan ni fún láti san owó ìtanràn .