+ -

عَنْ جَابِرِ بْنِ عَبْدِ اللَّهِ رضي الله عنهما أَنَّ النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«أُعْطِيتُ خَمْسًا لَمْ يُعْطَهُنَّ أَحَدٌ قَبْلِي: نُصِرْتُ بِالرُّعْبِ مَسِيرَةَ شَهْرٍ، وَجُعِلَتْ لِي الأَرْضُ مَسْجِدًا وَطَهُورًا، فَأَيُّمَا رَجُلٍ مِنْ أُمَّتِي أَدْرَكَتْهُ الصَّلاَةُ فَلْيُصَلِّ، وَأُحِلَّتْ لِي المَغَانِمُ، وَلَمْ تَحِلَّ لِأَحَدٍ قَبْلِي، وَأُعْطِيتُ الشَّفَاعَةَ، وَكَانَ النَّبِيُّ يُبْعَثُ إِلَى قَوْمِهِ خَاصَّةً وَبُعِثْتُ إِلَى النَّاسِ عَامَّةً».

[صحيح] - [متفق عليه] - [صحيح البخاري: 335]
المزيــد ...

Láti ọdọ Jaabir ọmọ Abdullahi kí Ọlọhun yọnu sí awan méjèjì, dájú dájú anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá Rẹ má bà sọ pé:
« wan tí fún mí ni nkán márùn tí wan kọ fún ẹni kánkan síwájú mí : wan fí ọwọ àti igbakẹ kankan mú aranse ba mí

[O ni alaafia] - [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 335]

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ àti ọlá Ọlọhun máa ba fún wa miró pé dájú dájú Ọlọhun ti fún òun ni nkán márùn tí Ọlọhun kọ fún ẹnikan nínú awani anọbi síwájú rẹ:
Alakọkọ: wan ràn mise pẹlu ìbẹrù tí wan nju sínú ọkan awàn ọtá mí , kò dá kí o já sipe kí Jinan mí sí ìbi tí wan wa le gbani ni irinajo osù kàn gbáko.
Ẹlẹẹkeji: wan se ilẹlẹ ni ààyè ifori kanlẹ fún wa tí a o máa kirun níbi kí bí tí a ba wa, wan tún se ni nkán imọra pẹlu lílo iyẹpẹ nígbàtí a bà kagara láti lọ omi.
Ẹlẹkẹta: wan se ọrọ ogún lẹtọ fún wa , òun ni nkan tí awàn musulumi nri gbà ní ojú ogún pẹlu awan alaigbagbọ.
Ẹlẹkẹrin: wan fun mí ni isipẹ tí o to bi jùlọ níbi ìfun awan ènìyàn ni ìsimi níbi ìbẹrù bojo ibuduro ọjọ igbende.
Ẹlẹkaarun: wan ràn mí sí gbogbo ẹda lapapọ àti eniyan àti alujannu wan yatọ sí ti awan anọbi tí wan síwájú rẹ, wan ran wan sí awan ìjọ wan nìkan ní .

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Biba òfin ẹṣin Islam mu pé kí ẹrú máa se onka awan idẹra tí Ọlọhun ṣe fún láti sọ jáde , àti láti fí ọpẹ fún Ọlọhun lórí idẹra náà.
  2. Ọlá Ọlọhun tí o gbangban tí o sí tóbi lórí ìjọ yí àti èyí to ṣe fún anọbi wa pẹlu awan nkán tí o da se fún wanyi.
  3. Ṣíṣe kikun ni àsìko rẹ ní ọranyan pẹlu èyí k'eyi isesi tí kìí baa jẹ , àti ṣíṣe awàn nkán tí ipa ba ka nínú awani monjẹmu rẹ ati awon origun pẹlu ọranyan rẹ.
  4. Orisirisi mí Isipẹ tí wan dá fun anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá Rẹ má bà láàrin awan anọbi :
  5. Alakọkọ ni : ṣíṣe ipẹ rẹ fún gbogbo ẹda láti ṣe ìdájọ láàrin won lasiko. Nínú rẹ ní isipẹ rẹ fún awán ọmọ alujanna láti wíwọ ọgbà idẹra , nínú rẹ tún ni : isipẹ rẹ fún ẹgban bàbá rẹ tii se Bàbá Tolib pé kí wan se ìyá rẹ ní fufu yẹ, , tí kí se isipẹ fún kí o jáde kúrò ninú inan, nítorípé o ku ni a lai gbagbọ .
  6. Awan ìròyìn ẹsa anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba pọ tí wan ko darukọ nínú hadith ( ọrọ anọbi ) yí , nínú rẹ ní ; wan fún ní ìgbé ọrọ kalẹ tí yóò kò ọpọ nkán sínú, òun sí ni wan parí awan anọbi, wan si tún se tito ila wa lori Irun gẹgẹ bí tito ila awan iransẹ Ọlọhun (Malaikah ) àti awan ìròyìn ẹsa bẹbẹ lọ
Ìtumọ̀ sí èdè mìíràn: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Èdè Indonéṣíà Èdè Uyghur Èdè Bangali Èdè Faransé Èdè Tọ́kì Èdè Rọ́ṣíà Èdè Bosnia Èdè Sinhala Èdè India Èdè Ṣáínà Èdè Páṣíà Èdè Vietnamese Èdè Tagalog Ti Kurdish Èdè Hausa Ti Pọtuga Malayalam Èdè Telgu Ti èdè Sawahili Tamil Thai Ede Jamani Pashto Assamese Ede Alibania Titi Sweden Ìtumọ̀ sí èdè Amharic Ìtumọ̀ sí èdè Dutch Titi èdè Gujarat Ti èdè Kyrgyz Ti èdè ìlú Nepal Ti èdè Lithuania Ti èdè Dari Ti èdè ìlú Serbia Ti èdè Rwanda Ti èdè ìlú Romania Ti èdè ilu Hungary الموري Ti ede Madagascar Ti èdè ẹ̀yà Oromo Ti èdè Kannada الولوف Ti èdè ìlú Ukraine الجورجية المقدونية الخميرية الماراثية
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn