Ìsọ̀rí ti ẹka

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ọlọhun a mu u wọ al-jannah lori èyíkéyìí iṣẹ ti o ba wa lori rẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ẹniti ó bá pade Ọlọhun ni ẹniti kò mú orogun kankan pẹlu Rẹ̀, onitọhun yoo wọ Alujanna, ṣugbọn ẹniti ó bá pade Rẹ̀ ni ẹniti ó mú orogun pẹlu Rẹ̀, onitọhun yoo wọ Ina
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi dámilójú pé oun yóò ṣọ́ nkan tí n bẹ láàrín eegun ẹnu rẹ méjèèjì àti nkan tí n bẹ láàrín ẹsẹ̀ rẹ méjèèjì, èmi yóò fi dá a lójú pé yoo wọ Alujanna
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Alujanna súnmọ́ ìkọ̀ọ̀kan nínú yín ju okùn bàtà rẹ̀ lọ, Iná naa sì rí bẹ́ẹ̀
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Wọ́n fi awọn adùn tí eniyan n fẹ́ nifẹkufẹẹ rọkirika Iná ọ̀run, wọ́n sì fi awọn nkan tí ọkàn eniyan koriira rẹ̀ rọkirika Alujanna
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Wọn bi ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- leere nipa nǹkan ti o maa mu awọn èèyàn wọ alujanna julọ, o sọ pe: “Ìpayà Ọlọhun ati iwa dáadáa
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Nígbà tí Ọlọhun da alujanna ati ina, O ran Jibril- ki ọla
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Awọn iran eniyan meji kan wa ninu ara ina ni wọn, mi ko ri wọn, ijọ kan ni ti awọn ọrẹ n bẹ pẹlu wọn ti wọn da gẹgẹ bi awọn iru maluu ti wọn maa n fi i na awọn eniyan, ati awọn obinrin kan wọn maa wọ aṣọ wọn si maa wa ni ihoho, ti wọn maa n mu ẹlòmíràn yẹ gẹrẹ, ti awọn gan ti yẹ̀ gẹ̀rẹ̀
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ẹyin àpapọ obinrin ẹ má ṣe itọrẹ àánù nítorí pé mori pé ẹyin ni awọn eniyan ti won pọ jù nínú ìlànà " ni wàn bà sọ pé: nitori kini ati pé kíni ọ fa irẹ ojisẹ Ọlọhun? ni ọ bá sọ pé: " Ẹ má nṣe pé púpọ̀ bẹ ni ẹ má nṣe aimoore sí àwọn ẹbí , mi ọ ri awọn obinrin ti wan dínkù ni ọpọlọ àti ní ẹṣin ti wan le gbà ọpọlọ ọkunrin ti ogban bere bere to dá bi ti ẹyin obìnrin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Wọn maa mu ikú wá ni ìrísí àgbò ti o ni dúdú ati funfun lára
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Iná yin jẹ ẹ̀yà kan nínú ẹ̀yà àádọ́rin ti ina Jahannama ni
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu