+ -

عَن أَبِي سَعِيدٍ الخُدْرِيَّ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«إِذَا وُضِعَتِ الجِنَازَةُ وَاحْتَمَلَهَا الرِّجَالُ عَلَى أَعْنَاقِهِمْ فَإِنْ كَانَتْ صَالِحَةً قَالَتْ: قَدِّمُونِي، وَإِنْ كَانَتْ غَيْرَ صَالِحَةٍ قَالَتْ: يَا وَيْلَهَا أَيْنَ يَذْهَبُونَ بِهَا؟ يَسْمَعُ صَوْتَهَا كُلُّ شَيْءٍ إِلَّا الإِنْسَانَ، وَلَوْ سَمِعَهُ صَعِقَ».

[صحيح] - [رواه البخاري] - [صحيح البخاري: 1314]
المزيــد ...

Láti ọdọ bàbá Sa'eed Al-kuhdiry kí Ọlọhun yọnu sí dájú dájú òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá Rẹ má bà s'ọpe:
« Tí wan ba gbé òkú kalẹ tí awàn ènìyàn (Ọkunrín ) gbé si gbee sí ọrùn wan , tí o ba se pé ẹniire ni yóò sọpe : ẹtete tí mí síwájú, tí o ba se pé kìí se eniire yóò sọ pé : ha o má se fún òunh nibo ni wan ngbé òunh lọ bayi? Gbogbo nkán ni yóò má gbọ òunh rẹ ayaafi ènìyàn nìkan, tí ènìyàn a gbọ òunh rẹ ní wan ba daku ni » .

[O ni alaafia] - [Bukhaariy gba a wa] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 1314]

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba fún wa niro pé tí wan ba gbé òkú kalẹ lórí ibùsùn, tí awàn eniyan l'ọkunrin sí gbé sórí ọrùn wan , tí o ba ṣepe ẹniire ni yóò sọ pé: etimi síwájú sí bí idẹra tí o wa níwájú rẹ, tí kí baa se eniire yóò parí wo pẹlu òunh tí arà kọ pé : ìparun tí dé ba òun nibo ni wan ngbé òunh lọ yì ?! Nitori ìyá tí o tiri ni iwájú rẹ, gbogbo nkán ni yóò gbọ òunh rẹ ayaafi ènìyàn, tí ènìyàn ba gbọ kò bà daku lẹkan náà latara lilagbara nkán to fí etí ará rẹ gbọ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Okú tí o jẹ ẹniire yóò máa ri awan ìfun ni ní ìró ayọ síwájú kí wan to ṣin , bẹẹ ni alaigbagbọ yóò máa tara párá, yóò sí máa ri Idakeji òun tí ẹniire rí .
  2. Díẹ nínú awàn òunh ni awan ẹda tí o yatọ sí ènìyàn má ngbọ , bẹẹ sí ní awan ènìyàn kòní le gbọ
Ìtumọ̀ sí èdè mìíràn: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Èdè Indonéṣíà Èdè Uyghur Èdè Bangali Èdè Faransé Èdè Tọ́kì Èdè Rọ́ṣíà Èdè Bosnia Èdè Sinhala Èdè India Èdè Ṣáínà Èdè Páṣíà Èdè Vietnamese Èdè Tagalog Ti Kurdish Èdè Hausa Ti Pọtuga Èdè Telgu Ti èdè Sawahili Tamil Thai Pashto Assamese Ìtumọ̀ sí èdè Amharic Ìtumọ̀ sí èdè Dutch Titi èdè Gujarat Ti èdè Dari Ti èdè ìlú Romania Ti èdè ilu Hungary Ti ede Madagascar الولوف Ti èdè ìlú Ukraine الجورجية المقدونية الخميرية الماراثية
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn