عن حذيفة رضي الله عنه قال: سمعت النبي صلى الله عليه وسلم يقول:
«لَا يَدْخُلُ الْجَنَّةَ قَتَّاتٌ».

[صحيح] - [متفق عليه] - [صحيح البخاري: 6056]
المزيــد ...

Láti ọ̀dọ̀ Huzaefah- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Mo gbọ ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe:
“Olófòfóó ko nii wọ alujanna”.

[O ni alaafia] - [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 6056]

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé olofofoo ti n gbe ọ̀rọ̀ kiri láàrin àwọn èèyàn láti da àárín wọn rú, pe iru ẹni bẹẹ ni ẹtọ si ìjìyà pe ko nii wọ alujanna.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Òfófó wa ninu awọn ẹṣẹ ńlá.
  2. Kikọ ofofo ṣíṣe; tori ibajẹ ati ìnira laarin ẹni kọọkan ati awọn janmọọn ti o wa ninu ẹ.
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn
Èdè: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Àlékún (67)