عَنِ شُرَيْحٍ بنِ هانِئٍ قَالَ:
سَأَلْتُ عَائِشَةَ، قُلْتُ: بِأَيِّ شَيْءٍ كَانَ يَبْدَأُ النَّبِيُّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ إِذَا دَخَلَ بَيْتَهُ؟ قَالَتْ: بِالسِّوَاكِ.
[صحيح] - [رواه مسلم] - [صحيح مسلم: 253]
المزيــد ...
Lati ọdọ shureih ọmọ Haani'i o sọ pé:
Mo bi Aishah leere, mo sọ pé: kini nkan akọkọ ti Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba) ma nṣe ti o ba wọlé rẹ? Aishah daun pe: yoo kọkọ rin pako.
[O ni alaafia] - [Muslim gba a wa] - [Sọhiihu ti Muslim - 253]
O tiwa ninu imọna Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati Ọla Rẹ máa ba a) pé kí o kọkọ rin pako ti o ba wọlé rẹ ni eyi keyi asiko ni oru tabi ọsan.