Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

1. Dajudaju wọn ri arabinrin kan ti wọn ti pa ninu ọkan ninu awọn ogun ti Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- ja, nitori naa, ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- kọ pipa awọn obinrin ati awọn ọmọde
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
2. o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jade lati ọwọ ahun ni”
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
3. wan tí fún mí ni nkán márùn tí wan kọ fún ẹni kánkan síwájú mí
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
4. E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
5. Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu