Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Dajudaju nnkan ti mo n bẹru julọ nipa yin ni ẹbọ kekere" wọn sọ pe: Ki ni ẹbọ kekere irẹ ojiṣẹ Ọlọhun? O sọ pe: "Ṣekarimi ni
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
“Ìwọ Ọlọhun, ẹnikẹni ti o ba jẹ alaṣẹ lori nǹkan kan ninu ijọ mi, ti o wa fi ara ni wọn, ki O fi ara ni in, ẹnikẹni ti o ba jẹ alaṣẹ lori nǹkan kan ninu ijọ mi, ti o wa ṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú wọn, ṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú oun naa”
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o dara julọ ni iwa
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Dajudaju iwa Anabi Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – ni Kuraani
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Mi o ri ki anọbi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi máa fì rí eyin ọọkan rẹ, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu
Ṣé ki n sọ ọrọ kan fun yin nipa dajjal, ti Anabi kan ko sọ nipa rẹ ri fun ijọ rẹ? O jẹ olójú kan, o maa mu nnkan ti o da bii alujanna ati ina wa pẹlu rẹ,
عربي Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu