‏Aanu rẹ - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a-

1Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi 1

“Ìwọ Ọlọhun, ẹnikẹni ti o ba jẹ alaṣẹ lori nǹkan kan ninu ijọ mi, ti o wa fi ara ni wọn, ki O fi ara ni in, ẹnikẹni ti o ba jẹ alaṣẹ lori nǹkan kan ninu ijọ mi, ti o wa ṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú wọn, ṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú oun naa”