عَنْ صَفْوَانَ بْنِ مُحْرِزٍ قَالَ: قَالَ رَجُلٌ لِابْنِ عُمَرَ رضي الله عنهما كَيْفَ سَمِعْتَ رَسُولَ اللهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، يَقُولُ: فِي النَّجْوَى؟ قَالَ: سَمِعْتُهُ يَقُولُ:
«يُدْنَى الْمُؤْمِنُ يَوْمَ الْقِيَامَةِ مِنْ رَبِّهِ عَزَّ وَجَلَّ، حَتَّى يَضَعَ عَلَيْهِ كَنَفَهُ، فَيُقَرِّرُهُ بِذُنُوبِهِ، فَيَقُولُ: هَلْ تَعْرِفُ؟ فَيَقُولُ: أَيْ رَبِّ أَعْرِفُ، قَالَ: فَإِنِّي قَدْ سَتَرْتُهَا عَلَيْكَ فِي الدُّنْيَا، وَإِنِّي أَغْفِرُهَا لَكَ الْيَوْمَ، فَيُعْطَى صَحِيفَةَ حَسَنَاتِهِ، وَأَمَّا الْكُفَّارُ وَالْمُنَافِقُونَ، فَيُنَادَى بِهِمْ عَلَى رؤُوسِ الْخَلَائِقِ هَؤُلَاءِ الَّذِينَ كَذَبُوا عَلَى اللهِ».
[صحيح] - [متفق عليه] - [صحيح مسلم: 2768]
المزيــد ...
Lati ọdọ Sufwan ọmọ Muhriz o sọ pé: arakunrin kan sọ fún ọmọ Umar ki Olohun yọnusi awan mejeji bawo ni ọ se gbọ ojisẹ Ọlọhun kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má ba ṣe sọ: nipa iṣọrọ kẹlẹ kẹlẹ? O sọ pé: mo gbọ tí nsọ:
" Olugbagbọ òdodo yóò sunmọ Olúwa rẹ ti o gbángban ti o ga jùlọ ni ọjọ igbende, titi yóò fi gbé
[O ni alaafia] - [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni] - [Sọhiihu ti Muslim - 2768]
Anọbi kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má ba ti fún wà niro nípa bí Ọlọhun yóò ṣe kó ẹrù Rẹ ti jẹ olugbagbọ òdodo yọ ní ọjọ igbende, o wa sọ pé:
Olugbagbọ òdodo yóò sunmọ Olùwà rẹ ni ọjọ igbende ti yóò sì bò lasiri' ti ko ní jẹ ki awọn tó wà níbẹ mọn kọkọ rẹ, yóò wá ṣọ fún pè:
inje ẹsẹ bayi to ṣẹ ati ẹsẹ bayi.. yóò se afirinle awọn ẹsẹ tó wà láàrin ẹrù ati Olùwà rẹ.
yóò sọ pé: bẹ ni Olúwa.
Títí yóò fi di pé olugbagbọ òdodo yóò bẹrù yóò sì fòyà, ni Ọlọhun mimọ ni fún yóò sọ pé: Emi ti bo ọ lasiri'rẹ latiri bẹẹ ni ma ṣe aforijin rẹ fún ni ọjọ oni, ni wàn yóò bá fún takanda iṣẹ dàda rẹ.
Ṣugbọn alaigbagbọ ati olójú meji (munaafik) wan yóò pé wan lójú gbogbo awọn tó wà níbẹ: awani wanyi ni wan parọ mọn Olùwà wan , ẹ reti kẹ gbọ igbe jinan sikẹ Ọlọhun yóò ma ba awani alabosi.