عَنْ ‌عَبْدِ اللهِ بْنِ زَيْدٍ رضي الله عنه:
أَنَّ النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ تَوَضَّأَ مَرَّتَيْنِ مَرَّتَيْنِ.

[صحيح] - [رواه البخاري] - [صحيح البخاري: 158]
المزيــد ...

Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Zaid- ki Ọlọhun yọnu si i-:
Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji.

[O ni alaafia] - [Bukhaariy gba a wa] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 158]

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nigba mii ti o ba fẹ ṣe aluwala, o maa n fọ gbogbo orikee ninu awọn orikee aluwala lẹẹmeji, o maa fọ oju- ti gbigbo ẹnu ati fifa omi simu n bẹ nibẹ- ati ọwọ mejeeji ati ẹsẹ mejeeji lẹẹmeji.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Eyi ti o jẹ dandan ni fifọ awọn orikee lẹẹkan ati pe eyi ti o ba lekun jẹ nnkan ti a fẹ.
  2. Ṣíṣe lofin ṣíṣe aluwala lẹẹmeji meji nigba mii.
  3. Nnkan ti a ṣe lofin nibi pipa ori ni ẹẹkan.
Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn
Èdè: Èdè Gẹ̀ẹ́sì Èdè Urdu Èdè Sípéènì Àlékún (58)