عَنْ أَبِي سَعِيدٍ الخُدْرِيِّ رضي الله عنه قَالَ: خَرَجَ رَسُولُ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ فِي أَضْحَى أَوْ فِطْرٍ إِلَى المُصَلَّى، فَمَرَّ عَلَى النِّسَاءِ، فَقَالَ:
«يَا مَعْشَرَ النِّسَاءِ، تَصَدَّقْنَ، فَإِنِّي أُرِيتُكُنَّ أَكْثَرَ أَهْلِ النَّارِ» فَقُلْنَ: وَبِمَ يَا رَسُولَ اللَّهِ؟ قَالَ: «تُكْثِرْنَ اللَّعْنَ، وَتَكْفُرْنَ العَشِيرَ، مَا رَأَيْتُ مِنْ نَاقِصَاتِ عَقْلٍ وَدِينٍ أَذْهَبَ لِلُبِّ الرَّجُلِ الحَازِمِ مِنْ إِحْدَاكُنَّ»، قُلْنَ: وَمَا نُقْصَانُ دِينِنَا وَعَقْلِنَا يَا رَسُولَ اللَّهِ؟ قَالَ: «أَلَيْسَ شَهَادَةُ المَرْأَةِ مِثْلَ نِصْفِ شَهَادَةِ الرَّجُلِ» قُلْنَ: بَلَى، قَالَ: «فَذَلِكِ مِنْ نُقْصَانِ عَقْلِهَا، أَلَيْسَ إِذَا حَاضَتْ لَمْ تُصَلِّ وَلَمْ تَصُمْ» قُلْنَ: بَلَى، قَالَ: «فَذَلِكِ مِنْ نُقْصَانِ دِينِهَا».
[صحيح] - [متفق عليه] - [صحيح البخاري: 304]
المزيــد ...
Láti ọdọ bàbá Sa'eed Al-Khudriy kí Ọlọhun yọnu si o sọ pé: òjíṣẹ Ọlọhun (ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bà) jáde nínú odun ileya tabi nínú ọdún ìtùnú awẹ lọ sí ààyè ìkìrun, ni o bá rè kọjá lẹgbẹ awọn obinrin ni o bá sọ pé:
" Ẹyin àpapọ obinrin ẹ má ṣe itọrẹ àánù nítorí pé mori pé ẹyin ni awọn eniyan ti won pọ jù nínú ìlànà " ni wàn bà sọ pé: nitori kini ati pé kíni ọ fa irẹ ojisẹ Ọlọhun? ni ọ bá sọ pé: " Ẹ má nṣe pé púpọ̀ bẹ ni ẹ má nṣe aimoore sí àwọn ẹbí , mi ọ ri awọn obinrin ti wan dínkù ni ọpọlọ àti ní ẹṣin ti wan le gbà ọpọlọ ọkunrin ti ogban bere bere to dá bi ti ẹyin obìnrin ", ni wàn bà sọ pé : irẹ ojisẹ Ọlọhun kíni idinku ẹṣin ati ọpọlọ wà? ni ọ bá sọ pé : " ṣe bi ìdajì ijẹri obinrin kan ni ijẹri ti okunrin " ? wàn ni bẹni, eléyìun ní wa nínú ẹdikun ọpọlọ rẹ, wan ni bẹẹ ni, O tun ni : Sebi ti obirin ba nṣe ikan osu rẹ kii kirun bẹẹ ni ko ni gba aawe ? wàn ni bẹẹ ni , o sọ pé eléyun náà wà nínú idikun ẹṣin rẹ ,
[O ni alaafia] - [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni] - [Sọhiihu ti Bukhaariy - 304]
Anọbi kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má bà jáde ní ọjọ odun kan lọ sí ààyè ìkìrun, bẹ sí ní otí se adeun fún awọn obinrin pé òun yóò dá ṣe isiti fún wan o sí pé adeun náà ni ọjọ náà , o wa sọ pé: Êyin àpapọ obìnrin ẹ má ṣe itọrẹ àánu ki ẹ́ sí ma tọrọ ọpọlọpọ aforinjin, mejeji wa nínú òkùnfà tótó bi lati fi ni ẹsẹ kúrò, nítorípé mori mori pé ẹyin ni ê pọ jù nínú inan ni òru ti mo se irin ajo òru.
ni arabinrin kan nínú wàn ti o ni ọpọlọ àti ọgbọn ati ifara balẹ: bá so pé: kíni o ṣe wà to fi jasi pe awa papọ ninu Inán irẹ ojisẹ Ọlọhun?
O sọ pé : nítorí awan nkan nkan : ẹ má nṣe pé ati èébìu, ẹẹ sí má ntako ẹtọ ọkọ. lẹyìn náà ni o ròyìn wan pẹlu gbólóhùn rẹ ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má bà: mi o ri awọn eniyan kan ti wan dínkù ni ọpọlọ àti ní ẹṣin ti wan lè borí ẹni tó lọpọ lọ l'ọkunrin tomura gírí to le to dàda to f'ẹsẹ rinlẹ dàda to bi eyin obirin rwan yi
O ṣọ pe Irẹ òjíṣẹ Ọlọhun, kíni idinku ọpọlọ àti ẹṣin ?
Ṣugbọn idinku ọpọlọ òun ni ijẹri obìrin méjì tí o ṣe dédé ijẹri ọkunrin kan soso , eleyi ni idinku ọpọlọ idinku ẹṣin òun ni idinku iṣẹ rere nigbati yóò lo àwon ọjọ ati oru kan ti lo ni fi kirun nítorí inkan osu , bẹẹ ni koni gba awọn ọjọ kan 'inu Ramadan nítorí inkan osu , eleyi ni idinku ẹṣin , o kan je pe wan ọ ni bú wàn tabi jẹ wan níyà nítorí bẹ , torípé ará ìpìlẹ àdámọ́ lojẹ, gẹgẹ bí wan se da inifẹ owo , ikanju ní bí àwọn àlámọrí, aimọkan ati bẹ bẹ lọ mọ ọmọ eniyan , ṣugbọn o pé akiyesi lori rẹ ki o le jẹ ìkìlọ ati iṣọrọ ki a le má ni idamu pelu awọn obirin ni .